Majemu Pipe Eniyan kan ni Keferi(Religion & Spirituality)

Ibanisoro yii da lori awon majemu ti a gbodo ri lara musulumi kan ki a to le pe ni Keferi, ti Olubanisoro si bere pelu nkan ti pipe Musulumi kan ni keferi tumo si ninu Islam.

Episodes : 1

Loading..